Font Size
Ìṣe àwọn Aposteli 16:17
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ìṣe àwọn Aposteli 16:17
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
17 Òun náà ni ó ń tọ Paulu àti àwa lẹ́hìn, ó sì ń kígbe, pé, “Àwọn ọkùnrin wọ̀nyí ni ìránṣẹ́ Ọlọ́run Ọ̀gá-ògo, tí ń kéde ọ̀nà ìgbàlà fún yin!”
Read full chapter
Heberu 7:1
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Heberu 7:1
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Melkisedeki jẹ́ àlùfáà
7 (A)Nítorí Melkisedeki yìí, ọba Salẹmu, àlùfáà Ọlọ́run Ọ̀gá-ògo, ẹni tí ó pàdé Abrahamu bí ó ti ń padà bọ̀ láti ibi pípa àwọn ọba, tí ó sì súre fún un,
Read full chapter
Marku 1:24
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Marku 1:24
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
24 (A)“Kí ni ìwọ ń wá lọ́dọ̀ wa, Jesu ti Nasareti? Ṣé ìwọ wá láti pa wá run ni? Èmí mọ ẹni tí ìwọ í ṣe; Ìwọ ní ẹni Mímọ́ Ọlọ́run!”
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.