Font Size
Jeremiah 51:7
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Jeremiah 51:7
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
7 (A)Ife wúrà ni Babeli ní ọwọ́ Olúwa;
ó sọ gbogbo ayé di ọ̀mùtí.
Gbogbo orílẹ̀-èdè mu ọtí rẹ̀,
wọ́n sì ti ya òmùgọ̀ kalẹ̀.
Gẹnẹsisi 19:24
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Gẹnẹsisi 19:24
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
24 (A)Nígbà náà ni Olúwa rọ̀jò iná àti Sulfuru (òkúta iná) sórí Sodomu àti Gomorra—láti ọ̀run lọ́dọ̀ Olúwa wá.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.