Font Size
Johanu 7:50
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Johanu 7:50
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
50 (A)Nikodemu ẹni tí ó tọ Jesu wá lóru rí, tí ó sì jẹ́ ọ̀kan nínú wọn sì sọ fún wọn pé,
Read full chapter
Johanu 19:39
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Johanu 19:39
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
39 (A)Nikodemu pẹ̀lú sì wá, ẹni tí ó tọ Jesu wá lóru lákọ̀ọ́kọ́, ó sì mú àdàpọ̀ òjìá àti aloe wá, ó tó ìwọ̀n ọgọ́ọ̀rún lítà.
Read full chapter
Luku 23:13
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Luku 23:13
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
13 Pilatu sì pe àwọn olórí àlùfáà àti àwọn olórí àti àwọn ènìyàn jọ.
Read full chapter
Johanu 7:26
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Johanu 7:26
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
26 Sì wò ó, ó ń sọ̀rọ̀ ní gbangba, wọn kò sì wí nǹkan kan sí i. Àwọn olórí ha mọ̀ nítòótọ́ pé, èyí ni Kristi náà?
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.