Font Size
Luku 2:21
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Luku 2:21
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
A gbé Jesu kalẹ̀ nínú Tẹmpili
21 (A)Nígbà tí ọjọ́ mẹ́jọ sì pé láti kọ ọmọ náà nílà, wọ́n pe orúkọ rẹ̀ ní Jesu, bí a ti sọ ọ́ tẹ́lẹ̀ láti ọ̀dọ̀ angẹli náà wá kí á tó lóyún rẹ̀.
Read full chapter
Johanu 1:29
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Johanu 1:29
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Jesu jẹ́ Ọ̀dọ́-Àgùntàn Ọlọ́run
29 (A)Ní ọjọ́ kejì, Johanu rí Jesu tí ó ń bọ̀ wá sí ọ̀dọ̀ rẹ̀, ó sì wí pé, “Wò ó, Ọ̀dọ́-àgùntàn Ọlọ́run, ẹni tí ó kó ẹ̀ṣẹ̀ ayé lọ!
Read full chapter
Ìṣe àwọn Aposteli 13:23
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ìṣe àwọn Aposteli 13:23
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
23 “Láti inú irú-ọmọ ọkùnrin yìí ni Ọlọ́run ti gbé Jesu Olùgbàlà dìde fún Israẹli gẹ́gẹ́ bí ìlérí.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.