Font Size
Matiu 5:31
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Matiu 5:31
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ìkọ̀sílẹ̀
31 (A)“A ti wí pẹ̀lú pé, ‘Ẹnikẹ́ni tí ó bá kọ aya rẹ̀ sílẹ̀, jẹ́ kí ó fi ìwé ìkọ̀sílẹ̀ lé e lọ́wọ́.’
Read full chapter
Matiu 19:7
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Matiu 19:7
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
7 (A)Wọ́n bi í pé: “Kí ni ìdí tí Mose fi pàṣẹ pé, ọkùnrin kan lè kọ ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀ nípa fífún un ní ìwé ìkọ̀sílẹ̀?”
Read full chapter
Marku 10:4
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Marku 10:4
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
4 (A)Wọ́n dáhùn pé, “Mose yọ̀ǹda fún wa láti kọ ìwé ìkọ̀sílẹ̀ fún un, kí a sì fi sílẹ̀.”
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.