Font Size
1 Kọrinti 1:8
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
1 Kọrinti 1:8
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
8 (A)Òun yóò sì mú yín dúró títí dé òpin, kí ẹ̀yin kí ó lè jẹ́ aláìlábùkù ní ọjọ́ Olúwa wa Jesu Kristi.
Read full chapter
1 Tẹsalonika 2:19
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
1 Tẹsalonika 2:19
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
19 (A)Kí ni ìrètí wa, ayọ̀ wa, tàbí adé wa nínú èyí tí a ó ṣògo níwájú Jesu Olúwa nígbà tí òun bá dé? Ṣé ẹ̀yin kọ́ ni?
Read full chapter
1 Tẹsalonika 4:17
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
1 Tẹsalonika 4:17
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
17 Nígbà náà ni a ó gba àwa tí ó sì wà láààyè sókè nínú àwọsánmọ̀ láti ọwọ́ Olúwa. A ó sì wà pẹ̀lú rẹ̀ títí láéláé.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.