Font Size
Kolose 1:19
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Kolose 1:19
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
19 Nítorí ìfẹ́ Ọlọ́run ni pé kí gbogbo ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ òun tìkára rẹ̀ lè máa gbé nínú rẹ̀.
Read full chapter
Kolose 2:9
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Kolose 2:9
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
9 Nítorí nínú Kristi ni ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìwàláàyè Ọlọ́run gbé ní ara,
Read full chapter
Efesu 1:23
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Efesu 1:23
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
23 (A)èyí tí i ṣe ara rẹ̀, ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ẹni tí ó kún ohun gbogbo ní gbogbo ọ̀nà.
Read full chapter
Romu 5:21
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Romu 5:21
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
21 (A)Pé, gẹ́gẹ́ bí ẹ̀ṣẹ̀ ti jẹ ọba nípa ikú bẹ́ẹ̀ ni kí oore-ọ̀fẹ́ sì lè jẹ ọba nípa òdodo títí ìyè àìnípẹ̀kun nípasẹ̀ Jesu Kristi Olúwa wa.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.